Isa 51:4 YCE

4 Tẹtilelẹ si mi, ẹnyin enia mi; si fi eti si mi, iwọ orilẹ-ède mi: nitori ofin kan yio ti ọdọ mi jade lọ, emi o si gbe idajọ mi kalẹ fun imọlẹ awọn enia.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:4 ni o tọ