Isa 53:6 YCE

6 Gbogbo wa ti ṣina kirikiri bi agutan, olukuluku wa tẹ̀le ọ̀na ara rẹ̀; Oluwa si ti mu aiṣedede wa gbogbo pade lara rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 53

Wo Isa 53:6 ni o tọ