Isa 54:5 YCE

5 Nitori Ẹlẹda rẹ li ọkọ rẹ; Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀; ati Olurapada rẹ Ẹni-Mimọ Israeli; Ọlọrun agbaiye li a o ma pè e.

Ka pipe ipin Isa 54

Wo Isa 54:5 ni o tọ