Isa 55:13 YCE

13 Igi firi yio hù jade dipò ẹgún, igi mirtili yio hù jade dipò oṣuṣu: yio si jẹ orukọ fun Oluwa, fun àmi aiyeraiye, ti a kì yio ke kuro.

Ka pipe ipin Isa 55

Wo Isa 55:13 ni o tọ