Isa 56:10 YCE

10 Afọju li awọn alore rẹ̀: òpe ni gbogbo wọn, odi ajá ni nwọn, nwọn kò le igbó, nwọn a ma sùn, nwọn ndubulẹ, nwọn fẹ ma tõgbé.

Ka pipe ipin Isa 56

Wo Isa 56:10 ni o tọ