Isa 56:8 YCE

8 Oluwa Jehofah, ẹniti o ṣà àtanu Israeli jọ wipe, Emi o ṣà awọn ẹlomiran jọ sọdọ rẹ̀, pẹlu awọn ti a ti ṣà jọ sọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 56

Wo Isa 56:8 ni o tọ