Isa 62:9 YCE

9 Ṣugbọn awọn ti o ṣà a jọ yio jẹ ẹ, nwọn o si yìn Oluwa; ati awọn ti nkó o jọ yio mu u, ninu ãfin mimọ́ mi.

Ka pipe ipin Isa 62

Wo Isa 62:9 ni o tọ