Isa 63:12 YCE

12 Ti o fi ọwọ́ ọtun Mose dà wọn, pẹlu apá rẹ̀ ti o logo, ti o npin omi meji niwaju wọn, lati ṣe orukọ aiyeraiye fun ara rẹ̀?

Ka pipe ipin Isa 63

Wo Isa 63:12 ni o tọ