Isa 64:11 YCE

11 Ile wa mimọ́ ati ologo, nibiti awọn baba wa ti nyìn ọ, li a fi iná kun: gbogbo ohun ãyo wa si ti run.

Ka pipe ipin Isa 64

Wo Isa 64:11 ni o tọ