Isa 64:5 YCE

5 Iwọ pade ẹniti nyọ̀ ti o nṣiṣẹ ododo, ti o ranti rẹ li ọ̀na rẹ: kiyesi i, iwọ binu; nitori awa ti dẹṣẹ̀; a si pẹ ninu wọn, a o ha si là?

Ka pipe ipin Isa 64

Wo Isa 64:5 ni o tọ