Isa 66:15 YCE

15 Nitori kiyesi i, Oluwa mbọ wá ti on ti iná, ati awọn kẹkẹ́ rẹ̀ bi ãjà, lati fi irunu sẹsan ibinu rẹ̀, ati ibawi rẹ̀ nipa ọwọ́ iná.

Ka pipe ipin Isa 66

Wo Isa 66:15 ni o tọ