Isa 66:23 YCE

23 Yio si ṣe, gbogbo ẹran-ara yio si wá tẹriba niwaju mi, lati oṣù titun de oṣù titun, ati lati ọjọ isimi de ọjọ isimi, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Isa 66

Wo Isa 66:23 ni o tọ