Isa 8:12 YCE

12 Ẹ máṣe pè gbogbo eyi ni imulẹ ti awọn enia yi pè ni imulẹ: bẹ̃ni ẹ máṣe bẹ̀ru ibẹ̀ru wọn, ẹ má si ṣe foya.

Ka pipe ipin Isa 8

Wo Isa 8:12 ni o tọ