Isa 8:18 YCE

18 Kiyesi i, emi ati awọn ọmọ ti Oluwa ti fi fun mi wà fun àmi ati fun iyanu ni Israeli, lati ọdọ Oluwa awọn ọmọ-ogun wá, ti ngbe òke Sioni.

Ka pipe ipin Isa 8

Wo Isa 8:18 ni o tọ