Isa 9:18 YCE

18 Nitori ìwa-buburu njo bi iná: yio jo ẹwọn ati ẹgún run, yio si ràn ninu pàntiri igbó, nwọn o si goke lọ bi ẹ̃fin iti goke.

Ka pipe ipin Isa 9

Wo Isa 9:18 ni o tọ