1 Sámúẹ́lì 1:11 BMY

11 Ó sì jẹ́jẹ̀ẹ́ wí pé, “Olúwa alágbára jùlọ tí ìwọ bá le bojú wo ìránṣẹ́-bìnrin rẹ kí ìwọ sì rántí rẹ̀, tí ìwọ kò sì gbàgbé ìránṣẹ́ rẹ ṣùgbọ́n tí iwọ yóò fún un ní ọmọkùnrin, nígbà náà èmi yóò sì fi fún Olúwa ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ a kì yóò sì fi abẹ kàn án ní orí.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1

Wo 1 Sámúẹ́lì 1:11 ni o tọ