1 Sámúẹ́lì 1:13 BMY

13 Hánà ń gbàdúrà láti inú ọkàn rẹ̀, ṣùgbọ́n ètè rẹ̀ ni ó ń mì, a kò gbọ́ ohùn rẹ̀. Élì rò wí pé ó ti mu ọtí yó.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1

Wo 1 Sámúẹ́lì 1:13 ni o tọ