2 Ó sì ní ìyàwó méjì: orúkọ wọn ni Hánà àti Pẹ̀nínà: Pẹ̀nínà ní ọmọ, ṣùgbọ́n Hánà kò ní.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1
Wo 1 Sámúẹ́lì 1:2 ni o tọ