1 Sámúẹ́lì 1:21 BMY

21 Ọkùnrin náà Elikánà, àti gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, gòkè lọ láti rúbọ ọdún sí Olúwa, àti láti sán ẹ̀jẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1

Wo 1 Sámúẹ́lì 1:21 ni o tọ