1 Sámúẹ́lì 10:26 BMY

26 Ṣọ́ọ̀lù náà padà sí ilé e rẹ̀ ní Gíbíà. Àwọn akọni ọkùnrin tí Ọlọ́run ti fi ọwọ́ tọ́ ọkàn wọ́n sì sìn ín.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:26 ni o tọ