1 Sámúẹ́lì 11:4 BMY

4 Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ náà sì wá sí Gíbíà tí ó jẹ́ ìlú Ṣọ́ọ̀lù, wọ́n sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àwọn ènìyàn, gbogbo wọn gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì sunkún.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 11

Wo 1 Sámúẹ́lì 11:4 ni o tọ