1 Sámúẹ́lì 11:6 BMY

6 Nígbà tí Ṣọ́ọ̀lù sì gbọ́ ọ̀rọ̀ wọn, ẹ̀mí Ọlọ́run sì bà lé e pẹ̀lú agbára, inú rẹ̀ sì ru sókè.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 11

Wo 1 Sámúẹ́lì 11:6 ni o tọ