1 Sámúẹ́lì 12:13 BMY

13 Nísinsìn yìí èyí ni ọba tí ẹ̀yin ti yàn, tí ẹ̀yin béèrè fún; wò ó, Olúwa ti fi ọba jẹ lórí yín.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:13 ni o tọ