1 Sámúẹ́lì 12:17 BMY

17 Òní kì í ha á ṣe ọjọ́ ìkórè ọkà àlìkámà bí? Èmi yóò ké pe Olúwa kí ó rán àrá àti òjò. Ẹ̀yin yóò sì mọ irú ohun búburú tí ẹ ti ṣe níwájú Olúwa nígbà tí ẹ̀ ń béèrè fún ọba.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:17 ni o tọ