1 Sámúẹ́lì 12:23 BMY

23 Bí ó ṣe ti èmi ni, kí á má rí i pé èmi dẹ̀ṣẹ̀ sí Olúwa nípa dídẹ́kun àti gbàdúrà fún un yín. Èmi yóò sì kọ́ ọ yín ní ọ̀nà rere àti ọ̀nà òtítọ́.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:23 ni o tọ