1 Sámúẹ́lì 12:9 BMY

9 “Ṣùgbọ́n wọ́n gbàgbé Olúwa Ọlọ́run wọn; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì tà wọ́n sí ọwọ́ àwọn Sísérà, olórí ogun Hásórì, àti sí ọwọ́ àwọn Fílístínì àti sí ọwọ́ ọba Móábù, tí ó bá wọn jà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:9 ni o tọ