13 Sámúẹ́lì sì wí fún un pé, “Ìwọ hu ìwà aṣiwèrè, ìwọ kò sì pa òfin tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ mọ́; bí o kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, òun ìbá fi ìdí ìjọba rẹ kalẹ̀ lórí Ísírẹ́lì láéláé.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13
Wo 1 Sámúẹ́lì 13:13 ni o tọ