1 Sámúẹ́lì 14:16 BMY

16 Àwọn tí ó ń ṣọ́nà fún Sàúlù ní Gíbéà ti Bẹ́ńjámínì sì rí àwọn ọmọ ogun ń túká ní gbogbo ọ̀nà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:16 ni o tọ