1 Sámúẹ́lì 14:35 BMY

35 Nígbà náà Ṣọ́ọ̀lù kọ́ pẹpẹ kan fún Olúwa; èyí sì jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe èyí.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:35 ni o tọ