1 Sámúẹ́lì 14:40 BMY

40 Nígbà náà ni Ṣọ́ọ̀lù wí fún gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, “Ẹ lọ sí apá kan; èmi àti Jónátanì ọmọ mi yóò lọ sí apá kan.”Gbogbo àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Ṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:40 ni o tọ