1 Sámúẹ́lì 15:20 BMY

20 Ṣọ́ọ̀lù sì wí fún Sámúẹ́lì pé, “Ṣùgbọ́n èmi ti ṣe ìgbọ́rán sí Olúwa, èmi sì ti lọ ní ọ̀nà tí Olúwa rán mi. Mo sì ti pa àwọn ará Ámálékì run pátapáta, mo sì ti mú Ágágì ọba wọn padà wá.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 15

Wo 1 Sámúẹ́lì 15:20 ni o tọ