1 Sámúẹ́lì 16:13 BMY

13 Nígbà náà ni Sámúẹ́lì mú ìwo òróró, ó sì ta á sí i ní orí ní iwájú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀, láti ọjọ́ náà lọ, Ẹ̀mi mímọ́ Olúwa wá sí orí Dáfídì nínú agbára. Sámúẹ́lì sì lọ sí Rámà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 16

Wo 1 Sámúẹ́lì 16:13 ni o tọ