1 Sámúẹ́lì 16:23 BMY

23 Ó sì ṣe, nígbà tí ẹ̀mi búburú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá bá dé sí Ṣọ́ọ̀lù, Dáfídì a sì fi ọwọ́ rẹ̀ kọrin lára dùùrù: a sì san fún Ṣọ́ọ̀lù, ara rẹ̀ a sì dá; ẹ̀mi búburú náà a sì fi sílẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 16

Wo 1 Sámúẹ́lì 16:23 ni o tọ