18 Kí o sì mú wàrà mẹ́wàá yìí lọ́wọ́ fún adarí ogun ti wọn. Wo bí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe wà kí o sì padà wá fún mi ní àmìn ìdánilójú láti ọ̀dọ̀ wọn.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17
Wo 1 Sámúẹ́lì 17:18 ni o tọ