1 Sámúẹ́lì 17:3 BMY

3 Àwọn Fílístínì sì wà ní orí òkè kan àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì wà ní orí òkè mìíràn, àfonífojì sì wà láàrin wọn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:3 ni o tọ