1 Sámúẹ́lì 17:36 BMY

36 Ìránṣẹ́ rẹ ti pa kìnnìún àti àmọ̀tẹ́kùn, aláìkọlà Fílístínì yìí yóò jẹ́ ọ̀kan lára wọn, nítorí ó ti pe ogun Ọlọ́run alààyè ní ìjà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:36 ni o tọ