1 Sámúẹ́lì 17:7 BMY

7 Ọ̀pá rẹ̀ rí bí apása ìhunṣọ, orí ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì wọn (600) kilogírámù méje irin, ẹni tí ó ru asà ogun rẹ̀ lọ ṣáájú u rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:7 ni o tọ