1 Sámúẹ́lì 18:27 BMY

27 Dáfídì àti àwọn arákùnrin rẹ̀ jáde lọ wọ́n sì pa igba lára àwọn Fílístínì. Ó kó awọ iwájú orí wọn wá, ó sì pé iye tí ọba fẹ́ kí ó baà lè jẹ́ àna ọba. Ṣọ́ọ̀lù sì fi ọmọ obìnrin Míkálì fún un ní aya.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 18

Wo 1 Sámúẹ́lì 18:27 ni o tọ