1 Sámúẹ́lì 19:15 BMY

15 Nígbà náà ni Ṣọ́ọ̀lù rán ọkùnrin náà padà láti lọ wo Dáfídì ó sì sọ fún wọn pé, “Mú wa fún mi láti orí ibùsùn rẹ̀ kí èmi kí ó le pa á.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:15 ni o tọ