1 Sámúẹ́lì 19:5 BMY

5 Ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wéwu nígbà tí ó pa Fílístínì. Olúwa ṣẹ́ ogun ńlá fún gbogbo Ísírẹ́lì, ìwọ rí i inú rẹ dùn. Èéṣe nígbà náà tí ìwọ yóò fi ṣe ohun búburú sí ọkùnrin aláìṣẹ̀ láìnídìí?”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:5 ni o tọ