1 Sámúẹ́lì 2:15 BMY

15 Pẹ̀lú, kí wọn tó sun ọ̀rá náà, ìráńṣẹ́ àlùfáà á dé, á sì wí fún ọkùnrin tí ó ń ṣe ìrúbọ pé, “Fi ẹran fún mi láti sun fún àlùfàá; nítorí tí kì yóò gba ẹran sísè lọ́wọ́ rẹ, bí kò se tútù.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2

Wo 1 Sámúẹ́lì 2:15 ni o tọ