20 Élì súre fún Elikánà àti aya rẹ̀ pé, “Kí Olúwa fún ọ ní irú-ọmọ láti ara obìnrin yìí wá, nítorí ẹ̀bùn tí ó béèrè tí ó sì tún fún Olúwa.” Wọ́n sì lọ sí ilé wọn.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2
Wo 1 Sámúẹ́lì 2:20 ni o tọ