1 Sámúẹ́lì 2:22 BMY

22 Élì sì di arúgbó gidigidi, ó sì gbọ́ gbogbo èyí ti àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe sí gbogbo Ísírẹ́lì; àti bi wọ́n ti máa ń bá àwọn obìnrin sùn, tí wọ́n máa ń péjọ ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2

Wo 1 Sámúẹ́lì 2:22 ni o tọ