1 Sámúẹ́lì 2:30 BMY

30 “Nítorí náà Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí pé, ‘Èmi ti wí nítòótọ́ pé, ilé rẹ àti ilé baba rẹ, yóò máa rìn níwájú mi títí.’ Ṣùgbọ́n nísinsin yìí Olúwa wí pé, ‘Kí á má rí i! Àwọn tí ó bú ọlá fún mi ni èmi yóò bu ọlá fún, àti àwọn tí kò kà mí sí ni a ó sì ṣe aláìkàsí.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2

Wo 1 Sámúẹ́lì 2:30 ni o tọ