17 Jónátanì mú kí Dáfídì tún ìbúra ṣe nítorí ìfẹ́ tí ó ní síi, nítorí tí ó fẹ́ ẹ gẹ́gẹ́ bí ó ti fẹ́ràn ara rẹ̀.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20
Wo 1 Sámúẹ́lì 20:17 ni o tọ