1 Sámúẹ́lì 20:24 BMY

24 Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì sá pamọ́ sínú pápá. Nígbà tí àṣè ìbẹ̀rẹ̀ oṣù tuntun sì dé, ọba sì jókòó láti jẹun.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:24 ni o tọ