36 Ó si wí fún ọmọdékùnrin rẹ̀ pé, “Sáré, kí o si wá àwọn ọfà tí èmi ó ta.” Bí ọmọdé náà sì ti ń sáré, òun sì tafà rékọjá rẹ̀.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20
Wo 1 Sámúẹ́lì 20:36 ni o tọ