1 Sámúẹ́lì 21:1 BMY

1 Dáfídì sì wá sí Nóbù sọ́dọ̀ Áhímélékì àlùfáà, Áhímélékì sì bẹ̀rù láti pàdé Dáfídì, ó sì wí fún un pé, “Èé ha ti rí tí o fi ṣe ìwọ nìkan, àti tí kò sì sí ọkùnrin kan tí ó pẹ̀lú rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 21

Wo 1 Sámúẹ́lì 21:1 ni o tọ