1 Sámúẹ́lì 21:11 BMY

11 Àwọn ìránṣẹ́ Ákíṣì sì wí fún un pé, “Èyí há kọ́ ní Dáfídì ọba ilẹ̀ náà? Ǹjẹ́ wọn kò ha ti dárin ti wọ́n sì gbe orin nítorí rẹ̀, tí wọ́n sì jó pé,“ ‘Ṣọ́ọ̀lù pá ẹgbẹ̀rún tírẹ.Dáfídì sì pa ẹgbàarún tirẹ̀’?”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 21

Wo 1 Sámúẹ́lì 21:11 ni o tọ