1 Sámúẹ́lì 21:13 BMY

13 Òun sì pa ìṣe rẹ̀ dà níwájú wọn, ó sì sọ ara rẹ̀ di aṣiwèrè ní ọwọ́ wọn, ó sì ń fi ọwọ́ rẹ̀ ha ilẹ̀kùn ojú ọ̀nà, ó sì ń wá itọ́ sí irungbọ̀n rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 21

Wo 1 Sámúẹ́lì 21:13 ni o tọ